Tiwa Savage, Ọba Orin Afrobeats, ńbá ètò ìtanijẹ tí a fí mú obìrin sìn wọ ìyá ìjà

  • Sep 05, 2021
instagram viewer

Afrobeats ti gba gbogbo U.S. kan, gbọ́n lọ́wọ́lọ́wọ́ níṣe ló dàbí ìgbà tí àwọn ọkùnrin nìkàn ló nkọrin yìí. B obìnrin kan dúró inṣin nínúu ẹ̀yà orin yìí: Tiwa Savage. po Èdè Gẹ̀ẹ́sì ati Yorùbá, èdè abínibí rẹ̀, pọ̀ lati yàka sí ètò ìtanijẹ tí a fí ńmú obìrin sìn. 'ń e gbogbo eléyìí láì lo ìyẹ̀fun-àtẹ́lẹ̀ pinpín.

gbà mẹ́ta gbáko ni iná mọ̀nàmọ́ná ọ̀dọ̀ Tiwa Savage kú mọ́ wa lójú nígbàtí a nṣe ìpàdé l'órí ẹ̀rọ ayélujára. Bẹ́ẹ̀ ní wọ́n ńṣaájò ní mẹ̀sǎn-mẹ́wǎ, "Ẹ má binú bí iná ṣe nkú mọ́wa lójú." Ọ̀rọ̀ wọn kúkú yé mi, àwa méjèèjì lajọ wà ní Ìlà Oòrùn Africa. Savage pè láti Lagos ni Nigeria, ibití wọn fi e ibùgbé lẹ̀hìn gbà tí Covid19 gb'ayé kan; èmi dẹ̀ ti wà ní Accra, Ghana, fún bíi oṣù mèjí tí mò fi ara ro ara pẹ̀lú àwọn ẹbí mi. Kí e ohun titun wípé Iná mọ̀nàmọ́ná ma ńṣe mọ́namọ̀na ni àwọn olúìlú naar wà ní Afrika. gbọ́n pẹ̀lú gbogbo wàhálà ọ̀hún, ìrẹ̀wẹ̀sì kò fi ìgbàkan bá ọkàn Savage, pẹ̀lú ọ̀yàyà ni wón fi mbá mi sọ̀rọ̀.

pàdé wà dá bíi kádàrá nítorípé àwọn orin Savage jẹ gẹ́gẹ́ bíi atọ́kùn, a tirẹ̀ lè pèé ní ìwé orin móríyá, tí ó fún mi ní gboyà láti dá atlántíkì kọjá pẹlú gbogbo ile àti ọ̀nà mi kúrò ní New York padà sí oríruùn ìyá mi. L'ọ́dún to kọjá àwọn orin rẹ fìdí múlẹ ṣinṣin sí oókan àyà mi, nitori ówùnmi jọjọ lati padà sí orísun mi. Mo fẹ́ kọ́ ìmọ̀ nípa ibi tí yá mí tí tọ̀ wá. wùn mi láti rí àwọn agboolé tí wọn bí ìyá-iya mi sí, nítorípé ìmọ yi e pàtàkì sí rìn àjò ilé-ayé mí.

Ní sán ọjọ́ nì, irun Savage, tí wọ́n pa láró pẹ̀lú àwọ̀ oyin, wà ní yiyá sókè. Níṣe ni àwọ̀ ara wọn, tí wọ́n fí bronzer fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ kùn, ńdán bíi fàdákà. Wn w aṣọ ìgba-òtútù èyí tí wọ́n f'ọwọ́ hun, lati ilé iṣẹ́ Burberry, níṣe ni aṣọún gun régérégé lara wọn. K sí ibikíbi ní abẹ́ ọ̀run tí Ọba orin Afrobeat àgbáyé yí kò tíì fi ẹsẹ tẹ láti ipasẹ̀ orin rẹ̀. Bí ọdún mẹwàá ni o ti nfi orin, ijó àti lù dá àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ lára ​​yá láti olú lú kan sí ìlú míràn káàkiri gbogbo àyé ńlá ayé. gbọ́n ní ọdún tí ókọjá ni ọba orin ti o kọ "Dangerous Love" ti wà ní orírun rẹ, Lagos, pẹlú ọmọ rẹ̀ Jamil. O dájú pé ó gbádùn bí ó e ráyè tọ́jú ọmọ rẹ̀, tí ó sì wà láàrin àwọn ẹbí rẹ̀, pẹ̀lú ìfọ̀kànbalẹ̀ láti pidán orin tuné nítorípóp Ọba orin fohùn sílẹ̀ wípé, "Bí mo ṣe wà nílé pẹ̀lú ọmọ mi, láì nílò ìṣojúlóge, tàbí kí n ma pá inú pó ní gbogbo ìgbà, tàbí kà n ma "

Wn jẹ́ ọ̀kan lára ​​àwọn ẹni tí ó buwọ́'lù ìwé pẹlú Motown Records, ọkàn lára ​​ikọ̀ tí ó ńbẹ labẹ àsìá Universal Music Group, Savage jẹ obìrin òṣèré ti ó gbayì jù l gbogbo. wé ìròyìn olóṣooṣù, Time Magazine, fún àkópọ̀ orin wọn ti àkọ́lé rẹ̀ ńjẹ́ Celia, ní ipò kẹwàá, nínú àwọn àkópọ̀ orin tó jáde ní ọdún 2020. Wn tí gba oríṣiríṣi oríyìn fún àwọn iṣẹ́ wọn, ogúnlọ́gọ̀ ènìyàn ló sì ma ńwo àwọn fídíò wọn. A ti fi ọmọ óókànlélógójì ọdún yí hàn ní America gẹ́gẹ́ bí ara àwọn "àjẹ́ olòrin ti yíó ra bí a ṣe ńkọrin padà tí ó sì jẹ́ ọmọ láti ilẹ̀ Afrika," Billboard ni ó e àfihàn yí l'ọdún to kọjá, ara àwọn olórin tí wọn ká mọ́ ẹgbẹ́ ìtèsíwájú yìí ní àwọn akọrin bíi Davido, Mr. Eazi, Burna Boy àti Wizkid.

gbọ́n bi Savage ṣe n fi ìmọ rẹ hàn nípasẹ àwọn òwe, ìfọ̀rọ̀wérọ̀ àti ọgbọ́n tí ó ńbẹ nínú orin wọn kó fi ara jọ agbára ìgbàlódé, tàbí. Nínú ìfòròwánilénuwò tí ó ṣe pẹlú Hot 97 ní oṣù Ògún, ọdún 2020, won sọ wípé, "Ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ ní tí o kọjá orin kíkọ́ lájànákori, nitori Wn tún wá yànàná ọ̀rọ̀ yìí síwájú síi, "[Ẹgbẹ́ ìgbélárugẹ Afrobeat] tí n fa ìfọwọ́sowọ́pọ̀, o sí ntọ ìlànà ìfẹ àti àjọṣepọ̀ láàrin orin ilu Caribbean, láàrin orin játi ó itihop ziel. Wn e àkójọpọ̀ gbogbo orin tí ó wà ní àgbà nlá aiyé tí ó ṣẹ̀ wá láti ọwọ́ àwa ènìyàn dúdú; ó jẹ́ kí a ní òye wípé gbogbo àwọn orin yi mú orísun wọn láti Africa."

Staat Lagos ni orílẹ̀-èdè Nigeria la bi Tiwatope Savage sí. Ni ìgbà tí ó pé ọmọ ọdún mọ́kànlá ní àwọn òbí rẹ̀ kó ilé àti ọnà wọn lọ sí ìlú London ní ibi tí Ọba orin wa ti bẹ̀rẹ̀ sí fi úfẹ hín f à máa k'ọrin, kí a sì máa pidán (ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún ni wọ́n jẹ nígbà tí wọn ṣe agberin lẹ́yìn òṣèré àgbáyé ìgbà kan rí George Michaël). gbọ́n awọn òbí wọn kúkú fi ye wín wípé wọ́n gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ mú ìwé kíkà ní ọ̀kúnkúndún. Nitori dí eléyìí ní wọ́n e gba degree accounting lati ilé wé gíga tí Unifásítì Kent.

Lyìn tí wọ́n e ìfẹ inú àwọn òbí wọn tán, wọ́n tún bẹ̀rẹ̀ sí gbáradì láti padà sí dí orin kíkọ́, ṣùgbọ́n lẹ́ẹ̀kan sìi àwọn òbí wọn Nínú ìfòròwánilénuwò wọn pẹlú Hot 97, Savage rántí oun ti àwọn òbí rẹ̀ sọ. "Wn sọ wípé, 'Tí ó bá jẹ́ ní tòótọ ní orin kíkọ́ jẹ́ ààyò rẹ, o gbọ́dọ̀ lọ ká ìwé nípa rẹ̀.'" Savage tún yànàná ọ̀rí nájáú s "Nítorí ìdí èyí ní mo ṣe bèèrè àyè ní ile ẹkọ Berkley [Ẹ̀ka ilé kọ́ gíga tí ó gbayì, Boston Music College], tí mo sì gbà scholarship lati kọ́ ìmọ̀ nípa kọ́b l san. san

Ní inú ìrìn àjò yìí ní Savage tí ṣe agberin lẹ́yìn àwọn ìràwọ̀ ńlá-ńlá, àwọn sànmọ́nì akọrin, lára ​​wọn ni Whitney Houston, Mary J. Blige, Chaka Khan àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. Ní ìgbà tí Savage ma fi dà dúró ní bii ọdún 2010, of tí di ọgá ní dí kí á fí ohùn dárà, àjọ Grammy sí tí yàán gẹ́gẹ́bíí ìkan níakú àwọn l'àwùjọ.

Plú ohùn kè ẹlẹgẹ́ bíi ti ológbùró, ti òye bí a ṣe di Èdè Yòrùbá pèlú Èdè Gẹ̀ẹ́sì pọ̀ láì f'ẹsẹ̀ kọ. ba orin Savage a máa kọ orin àròjinlẹ̀ tí ó m'ọ́gbọ́n wà nípa ọ̀rọ̀ ìfẹ, owó, òṣèlú àti ètò ìtanijẹ tí a fí ńmú obìrin sìn. Àwọn orin bi "Korobá" ní ibí tí wọ́n ti gbé ìlo agbára láàrin àwọn bàbá olówó àti ọmọdé'bìrin wò (Èmi ò w'áíyé wá jẹ ìyá/Tí mo bá pèé ní iṣẹ́ aṣẹ́wó/ t'ani kò fẹ́ràn ìgbáládùn?), tàbí "49-99" níbi tí wọ́n ti yànàná ọ̀rọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àti ìdibàjẹ́, Savage ni ó gbé dé. wọn atọ́kùn ètò bíi Blaq Jerzee, Pheelz, ati London ló ti ṣe àpòpọ̀ Sonic Fusion nínú orin Savage ti ó po ohun-èlò Afrobeats (fèèrè, kàkàkí, ìlú) pẹ̀lú okùn Synthesizer

Kaba IAMISIGO Floribunda. Tiffany & Co. Yerí. Lees meer: ​​Face Illuminator Highlighting Powder in Seduction, Lip Glacé in Bare Blush en Longer Lip Liner in Red Chocolate van Laura Mercier.

Ayàwòrán Lakin Ogunbanwo

Pẹlú ìmọ̀ àti ọ̀fintótó ni Savage e ngbé ará rẹ̀ lójú aráyé– láti irun orí rẹ̀, tí ó ńṣe ní ipasẹ̀ àwa ènìyàn dúdú èyí tí ó lò jùlọ nínú àwọn fídíò rẹ̀, dé bí wọ́n ṣe ǹ tanná sí àwọ̀ ara rẹ̀, èyí tí ó dúdú bíi kóró iṣin, lóríi ẹ̀rọ ayáwórán. ní ìdí tí Savage fi ńpè ara rẹ̀ ní "chocolade girl", èyí kò sí jìnà sí òye rẹ nípa ìkórira àwọ̀ ati ẹ̀tàn tí ó wà nínú bí àwọn òyìe sọ pé awẹ́lẹ́wà gbọdọ̀ rí bákan, ọlọ́pọlọ pípé ní Savage, ó sì mọ̀ wípé ọ̀rọ̀ pàlapàla àti ẹ̀tàn tí ó jẹ́ jàde láti ọwọ́ ìjọba amúnisìnó nee. "Ní tòótọ́ ni mo fẹ́ bòra ní ìgbà èwe mí, mo ṣì wà ní bíi ọmọ ọdún mẹ́rìnlà sí màrùndínlogún," óò tún sọ̀rọ̀ náà síwájú síi, "Tí síi di àárò ọ̀la, àwọn apá ibìkan l'ẹ̀yìn mi ṣi le… ìgbà tí ìyá mí ń tọ́jú iyàrá mi ni wọ́n rí àwọn ìpara tí mò ńpò pọ̀ pẹlú òrom̀bó wij Wij. Inú kò tilẹ̀ bi wọ́n. gbọ́n inú wọn kò dùn sí mí rárá, ojú dẹ̀ gbà wọ́n tí fún mi. torí náà ni mo ṣe pàá tí, ṣùgbọ́n fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ní mo fi kó'ìrira àwọ̀ dúdú mí."

Ní gbà tí àwọn sànmọ̀rí lú bẹ̀rẹ̀ síí fí ojú sí Savage lara ni ìyípadà rere bá bí o ṣe ńrí ara rẹ̀. "Nígbàtí mo kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin, mi ó l'áyà tó láti gba gbogbo àṣekún àti àṣekù mi nítorí wípé mo tilẹ̀ kọ́kọ́ fẹ́ di olórin tí ó gbayì." O sọ s'íwájú síi wípé, "Àwọn orin méjì tí mo kọ́kọ́ kọ lọ ní ìlànà ti America, ko f'ara jọ orin Afrika rárá. gbọ́n bí ogbọ́n e ńgun ọgbọ́n, mo bẹ̀rẹ̀ síí rí wípé àgbára ńbẹ nínú òkè tí mo gùn, àtí bíi àwọn abiyamọ yíò sọny wípé, 'Ọmọ mi m mi

Kaba IAMISIGO Floribunda

Nígbà tí wọ́n bá wà lórí ìtàgé-àrà wọ́n ma ńtiraka "láti hàn l'órí àwòrán bí mo ṣe ma hàn lójú aiyé," títí kan gbogbo àbàwọ́n ún wọn ara wọn Wn kò mú ayé le fún ara wọn nípasẹ̀ àìṣóòtọ́ àti ìtanijẹ, gbà mí bí o ṣe ńrí mi bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ wọn rí. ti wípé wà ká di itọ́ dúdú sínú, ká tu funfun jáde, kó bá atótilétọ̀ wọn lára ​​mu. "Mo ti wà l'àwùjọ àwọn bọ̀rọ̀kíní ìlú, nítorí náà mó ntiraka mọ́ ojúṣe mí fún àwọn ọ̀dọ́." Wn tún sọ wípé, "Mo wòye wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìfúngunmọ ló wà ní òde ìsìyín, yóò sì burú jáì l'órí àwùjọ ayélujára, een gbọ́dọ̀ wà ìdiwọ̀n leuk. Een ní láti wá àwọn èèyàn tí kò ṣebí wípé àwọn ti d'ápé jù. Mo mọ̀ wípé gbogbo wa la fẹ gbayì láwùjọ, a sì fẹràn oge. Kìí ṣe pé èmi náà fẹ́ dàbí ẹni tí kò bìkítà fún ara rẹ, ṣùgbọ́n àparò kan kò ga jù kan lọ, mo dẹ̀ fẹ́ kí àwọn olólùfẹ́ mi lé sùn mọ́ mi."

Ní gbà tí à ńṣe fòròwánilénuwò yìí, Savage sọ fún mi pẹ̀lú ìgboyà wípé àwọn kò tíì fí ìyẹ̀fun-àtẹ́lẹ̀ kan ojú àwọn fún ọdún méjì Yálà wọ́n wà n'ìlé, wọ́n jáde tàbí fún yíya àwòrán— bẹ́ẹ̀ni pẹlú àwòrán tí wọ́n yà fún ojú ewé kínní Allure— wọn kò lòó píìn. Ǹjẹ́ lára ​​ìfiraẹni hàn, gbà mí bí mo ṣe rí, wọn ni ípinnu yìí? Bẹ́ẹ̀ni, bẹ́ẹ̀ dẹ̀ tún kọ́: "Mo padé Naomi ní bíi ọdún mẹ́ta sẹ́hìn, nínú ọ̀rọ rẹ̀ o wípé ọ̀kan nínú àwọn oun tí kò lò mọ́ ni ìyẹ̀fun-àtẹ́l báwòo?' mi náà wá pinnu láti má lo ìyẹ̀fun-àtẹ́lẹ̀ mọ́." Ní tòótọ: Ìgbà kígbà tí Naomi ọmọ Campbell bá fún ní n'ìmọràn pàápàá lórí oun àmúàoge, gbàá. gbọ́n fún Savage oun ti ówùún ní àti dá wàhálà ọ̀hún kọjá. Yíyọ ìyẹ̀fun-àtẹ́lẹ̀ kúrò nínú hílàhílo ìṣètò wọ́n to ti kún fọ́nfọ́n tẹ́lẹ̀, bẹ́ẹ̀ kò yọ kúrò lára ​​ẹwà wọn. e ara ẹní lóge, bii ìrìn àjò ayé wọn nísìsiyìí, gbọ́dọ̀ jẹ́ ìtura. Wn sọ wípé, "Tí mbá ti rì Ìyẹ̀fun, blush, tìróò, àti ìkùntè, ó parí."

Savage jẹ́ olóòótọ, ọmọnìyàn, àti ní ìgbà míràn, yíó ma ṣe bii ọmọ ilè-íwè(ní ṣe ni wọ́n fi'ra. Wn ńsọ fún ọmọ wọn wípé "Bàbá in tuntun ló wò yẹn." Bí wọ́n ṣe ńwo Legend of the Blue Sea). Ohun tí wọ́n fi ọjọ́ wọn e ko ju kí wọ́n ka bíbélì, kí wọ́n wo Netflix, kí wọ́n ṣe àṣàrò fún ra wọn, àti kí wọ́n má lọ sí orí àwùjọ-ayélújár).

Wn tún ro bí wọ́n ṣé ma fi ọ̀rọ̀ to ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ làákàyè sí inú orin wọn. Nínú ìpele tuntun ayé wọn yìí, Savage fẹ mú àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ wọ ìrìn-àjò tí kò ní 'orin ìfẹ, àwọn orin tí ó dùn, tí a lèú rẹ́rìín m. L'ẹ́yín dún kan gbáko ti àwọn ọlọ́pàá tú ìbẹ̀rú b'ojo bá àwọn ará ìlú, tí ará-ìlú sì kọjú sí wọn pẹlú #EndSARS, àti ìpànìyàn tí óò ṣẹlẹ̀ ní Lekki Tollgate tí kò jìnà sí ilé rẹ̀, Savage tí dojú kọ àwọn oun tí ó ṣe patákì. Gbogbo dún tó kọjá ló fí wo ìròyìn àgbáyé tí ó sì bu ẹnu àtẹ́ lu àwọn ọ̀rọ̀ tó kù díẹ̀ káátó ní ilẹ̀ẹ Nigeria, àwọn nkán bíọ̀ ìfipá b bíọ̀ fipá Pẹ̀lú ìrètí wípé tí họ́ùhọ̀ù bá tán ní àwùjọ-ayélujára, ipá lati dá ààbò bo àwọn aláìní agbára kò ní tán. Ó' dá Ilé iṣẹ́ ọpọlọ We zijn moe, sílẹ̀ láti ṣe ìrànlọ́wọ́ òfin àti ìdáàbòbò fún àwọn tí orí yọ lẹyìn ìfipá báni lòpọ̀. ímọye ìgbà ní àwọn olóṣèlú àti olórí ẹ̀sìn binú sí orin Savage tí ó ńbá jẹgúdú-jẹrá wí. Ṣùgbọ́n fún Savage: "Kí kúkú ṣe wípé mó ńwá kí orin mí gbanájẹ, tàbí kó pariwo ní'lé ijó, tàbí kí ọ̀gọ̀lọgọ̀ ènìyàn fetí sí orin mi," wọ́n sọ̀rọ̀ síwájú wípé, "Ó dájú wípé gbogbo àgbáyé ní nkán bá lọ́wọ́lọ́wọ́ mo sì fẹ́ e ìwọnba tí mo le ṣe lati mú dára."

Meer informatie over Lagos Lati Tiwa Savage.

ràwọ̀ àgbáyé Afrobeats fún wa ni ọ̀rọ̀ kínkín to gbankọgbì— jẹ̀ o ti lo ọṣẹ dúdú láti Africa rí?— àkàpé ohùn àmúṣẹwà tiwantiwa tó fẹràn.

ILÉ ÌṢERUNLÓGE

TasalaHQ, 1, Muritala Mohammed Drive

Voormalige Bankweg,

Ikoyi, Lagos

"Wan mọ bí wọ́n e ńtún irun àwa ènìyàn dúdú ṣe dáadáa," Savage tún sọ̀rọ̀ síwájú síi. “Ẹẹ̀ bà ma wọ pruiken tàbí weaves ní gbogbo ìgbà, wọ́n máa condition ẹ̀ dáadáa débi pé irun yín máa gùn lábẹ́ rẹ̀.”

TÚNRAṢE SPA

B Natuurlijk Medisch

Spa, 11 Oduduwa Way, GRA, Ikeja, Lagos

Savage kìí ńsábà lọ sí spa, ṣùgbọ́n wọ́n fẹ́ràn láti máa gbádùn hamambehandeling (ìṣe àwọn Lárúbáwá tí ó kó ìpani láwọ̀- ati ìṣesí- dà, ìṣe yìí kó wiwẹ pẹlú omi híhó, afschilfering gbogbo ara, àti ìwọ́ra fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́). Ibíyìí ni wọ́n ti fẹ́ràn láti máa ṣe hammam ní Lagos, wọ́n sọ s'íwájú síi wípé, "Tì'n bá wà ní London, Harrods ni mo ma ńlọ."

ÌTÚNRAṢE ÀWÒPADÀSẸ́YÌN

R&R luxe vloeistof

Ọṣẹ Dudú

pópọ̀ Òòrí àti Àdín, ọṣẹ yìí wá láti ọwọ́ ọmọ tí a bí nílẹ̀ Nigeria, tí ó ńgbé ní Ghana, ẹ̀yà aṣàwọ̀lóge R&R Luxury jẹ́ kọ́kọ́rọ́ pàtàkì nínú ìṣàwọ̀lóge ojoojúmọ́ Savage: “Mo ma'ń fọ ojú mi [pẹ̀lúu rẹ̀], Ní ẹ̀kààkan mo ní oríṣiríṣi masks ti mo ma'ń ló láràárọ̀. Mo ma po ataàlẹ̀ àti oyin pọ̀, máà sí fi pa ojú fún bíi íṣẹ́jú márùdínlógún. Mo dẹ̀ tún ní ìbojú LED tí mo ma'ń lò laalé kàà kan.

Ayàwòrán: Lakin Ogunbanwo
Aaralóge: KK Obi
Olùrànwọ́ Aṣaralóge: Charles Ndiomu
Ik ren: Bernard Smiless
ojúlóge: Ruth Akele
Idán tàgé: Anti-ontwerp
pa: Funmbi Ogunbanwo
dúgbo: Clear Essence California Spa & Wellness Resort
dàkọ sí Yorùbá: Ayodele Olofintuade

ÌKÉDE ALÁBÀPÍN: tàn yìí kọ́kọ́ jáde ní Allure ìpele oṣù Èbíbí, ọdún 2021.Kọ ẹkọ bii o ṣe le ṣe alabapin nibi.

Om dit verhaal in het Engels te lezen,Klik hier.

insta stories